Àwọn Ọba Keji 14:26 BM

26 OLUWA rí i pé ìpọ́njú àwọn ọmọ Israẹli pọ̀, kò sì sí ẹni tí ìpọ́njú náà kò kàn, ati ẹrú ati ọmọ, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹni tí ó lè ràn wọ́n lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:26 ni o tọ