Àwọn Ọba Keji 14:27 BM

27 Bẹ́ẹ̀ sì ni OLUWA kò tíì sọ pé òun óo pa gbogbo Israẹli run, nítorí náà, ó ṣẹgun fún wọn láti ọwọ́ Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:27 ni o tọ