Àwọn Ọba Keji 19:18 BM

18 Ó ti dáná sun àwọn ọlọrun wọn; ṣugbọn wọn kì í ṣe Ọlọrun tòótọ́, ère lásán tí a fi igi ati òkúta gbẹ́ ni wọ́n, iṣẹ́ ọwọ́ ọmọ eniyan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:18 ni o tọ