Àwọn Ọba Keji 19:19 BM

19 Nisinsinyii OLUWA Ọlọrun wa, jọ̀wọ́ gbà wá lọ́wọ́ Asiria kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé lè mọ̀ pé ìwọ OLUWA nìkan ni ỌLỌRUN.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:19 ni o tọ