Àwọn Ọba Keji 19:34 BM

34 N óo gbèjà ìlú yìí, n óo sì dáàbò bò ọ́ nítorí ògo mi ati ìlérí tí mo ti ṣe fún Dafidi iranṣẹ mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:34 ni o tọ