Àwọn Ọba Keji 19:35 BM

35 Ní alẹ́ ọjọ́ náà ni angẹli OLUWA lọ sí ibùdó ogun Asiria, ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹsan-an lé ẹẹdẹgbaata (185,000) àwọn ọmọ ogun, wọn kú kí ilẹ̀ ọjọ́ keji tó mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:35 ni o tọ