Àwọn Ọba Keji 20:15 BM

15 Aisaya bá tún bèèrè pé, “Kí ni wọ́n rí ninu ààfin rẹ?”Ọba dáhùn, ó ní, “Kò sí ohun kan ninu ilé ìṣúra tí n kò fi hàn wọ́n.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:15 ni o tọ