Àwọn Ọba Keji 21:1 BM

1 Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hefisiba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:1 ni o tọ