Àwọn Ọba Keji 21:2 BM

2 Manase ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA nítorí pé ó tẹ̀lé ìwà ìríra àwọn eniyan ilẹ̀ náà, tí OLUWA lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:2 ni o tọ