Àwọn Ọba Keji 22:18 BM

18 Ṣugbọn níti ọba Juda tí ó sọ pé kí ẹ lọ wádìí lọ́wọ́ OLUWA, ẹ sọ fún un pé, OLUWA Ọlọrun Israẹli ní: Nípa ọ̀rọ̀ tí ó ti gbọ́, nítorí pé ó ronupiwada,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:18 ni o tọ