Àwọn Ọba Keji 22:17 BM

17 Nítorí pé wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n ń sun turari sí àwọn oriṣa láti mú mi bínú nítorí iṣẹ́ ọwọ́ wọn. Nítorí náà, inú mi yóo ru sí ibí yìí, kò sì ní rọlẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:17 ni o tọ