Àwọn Ọba Keji 23:30 BM

30 Àwọn olórí ogun rẹ̀ gbé òkú rẹ̀ sinu kẹ̀kẹ́ ogun kan láti Megido wọn gbé e wá sí Jerusalẹmu, wọ́n sì sin ín sinu ibojì rẹ̀.Àwọn eniyan Juda sì fi òróró yan Jehoahasi ọmọ rẹ̀ ní ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:30 ni o tọ