Àwọn Ọba Keji 23:31 BM

31 Ẹni ọdún mẹtalelogun ni Jehoahasi nígbà tí ó jọba ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún oṣù mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hamutali, ọmọ Jeremaya, ará Libina.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:31 ni o tọ