Àwọn Ọba Keji 23:34 BM

34 Neko sì fi Eliakimu, ọmọ Josaya, jọba dípò rẹ̀, ṣugbọn ó yí orúkọ rẹ̀ pada sí Jehoiakimu. Neko mú Jehoahasi lọ sí Ijipti, ibẹ̀ ni ó sì kú sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:34 ni o tọ