Àwọn Ọba Keji 23:35 BM

35 Jehoiakimu ọba gba owó orí lọ́wọ́ àwọn eniyan gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ wọn ti pọ̀ tó, láti rí owó san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba Ijipti gẹ́gẹ́ bí ó ti pa á láṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:35 ni o tọ