Àwọn Ọba Keji 23:36 BM

36 Jehoiakimu jẹ́ ẹni ọdún mẹẹdọgbọn nígbà tí ó jọba, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sebida, ọmọ Pedaaya, láti ìlú Ruma.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:36 ni o tọ