Àwọn Ọba Keji 24:1 BM

1 Ní àkókò ìjọba Jehoiakimu ni Nebukadinesari, ọba Babiloni gbógun ti Jerusalẹmu, Jehoiakimu sì di iranṣẹ rẹ̀ fún ọdún mẹta. Lẹ́yìn náà, ó pada lẹ́yìn Nebukadinesari, ó sì ṣọ̀tẹ̀ sí i.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:1 ni o tọ