Àwọn Ọba Keji 24:2 BM

2 OLUWA bá rán àwọn ọmọ ogun Kalidea, ati ti Siria, ti Moabu, ati ti Amoni, láti pa Juda run bí ọ̀rọ̀ ti OLUWA sọ láti ẹnu àwọn wolii, iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:2 ni o tọ