Àwọn Ọba Keji 24:13 BM

13 Ó kó gbogbo àwọn ìṣúra ilé OLUWA ati àwọn ìṣúra tí ó wà ní ààfin. Gbogbo ohun èèlò wúrà tí wọ́n wà ninu ilé OLUWA, tí Solomoni ọba Israẹli ṣe, ni ó gé sí wẹ́wẹ́, gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti sọ tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:13 ni o tọ