Àwọn Ọba Keji 24:14 BM

14 Ó kó gbogbo Jerusalẹmu ní ìgbèkùn; gbogbo àwọn ìjòyè, àwọn akọni, àwọn oníṣẹ́ ọwọ́, ati àwọn alágbẹ̀dẹ, gbogbo wọn jẹ́ ẹgbaarun (10,000), kò ṣẹ́ku ẹyọ ẹnìkan ní ìlú náà, àfi àwọn talaka.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:14 ni o tọ