Àwọn Ọba Keji 24:15 BM

15 Ó kó ọba Jehoiakini, ati ìyá rẹ̀, ati àwọn aya rẹ̀, àwọn ìwẹ̀fà rẹ̀ ati àwọn ìjòyè ilẹ̀ náà ní ìgbèkùn láti Jerusalẹmu lọ sí Babiloni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:15 ni o tọ