Àwọn Ọba Keji 24:16 BM

16 Ọba Babiloni kó ẹẹdẹgbaarin (7,000) àwọn akọni ní ìgbèkùn ati ẹgbẹrun kan (1,000) àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ ati alágbẹ̀dẹ, gbogbo wọn jẹ́ alágbára tí wọ́n lè jagun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:16 ni o tọ