Àwọn Ọba Keji 24:7 BM

7 Ọba Ijipti kò lè jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀ mọ́, nítorí pé ọba Babiloni ti gba gbogbo ilẹ̀ ọba Ijipti láti odò Ijipti títí dé odò Yufurate.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:7 ni o tọ