Àwọn Ọba Keji 24:8 BM

8 Ẹni ọdún mejidinlogun ni Jehoiakini nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún oṣù mẹta. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Nehuṣita, ọmọ Elinatani ará Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:8 ni o tọ