Àwọn Ọba Keji 25:13 BM

13 Àwọn ọmọ ogun Kalidea fọ́ àwọn òpó bàbà tí ó wà ninu ilé OLUWA ati agbada bàbà ńlá tí ó wà ninu ilé OLUWA pẹlu ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀, wọ́n fọ́ wọn sí wẹ́wẹ́, wọ́n sì kó gbogbo bàbà wọn lọ sí Babiloni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:13 ni o tọ