Àwọn Ọba Keji 25:14 BM

14 Wọ́n kó àwọn ìkòkò, àwọn ọ̀kọ̀, àwọn ọ̀pá tí wọ́n fi ń pa iná lẹ́nu àtùpà, àwọn àwo turari ati àwọn ohun èlò bàbà tí wọ́n máa ń lò fún ìsìn ninu ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:14 ni o tọ