Àwọn Ọba Keji 25:15 BM

15 Bákan náà, wọ́n kó àwọn àwo ìfọnná, ati àwọn àwo kòtò, gbogbo ohun tí ó jẹ́ ti wúrà ati fadaka, ni olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba Babiloni kó lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:15 ni o tọ