Àwọn Ọba Keji 4:40 BM

40 Wọ́n bu oúnjẹ fún àwọn ọmọ wolii láti jẹ. Bí wọ́n ti ń jẹ àsáró náà, wọ́n kígbe pé “Eniyan Ọlọrun, májèlé wà ninu ìkòkò yìí!” Wọn kò sì lè jẹ ẹ́ mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:40 ni o tọ