Àwọn Ọba Keji 4:6 BM

6 Nígbà tí gbogbo àwọn ìkòkò náà kún, obinrin náà bèèrè bóyá ìkòkò kù, àwọn ọmọ rẹ̀ sì dáhùn pé ó ti tán, òróró náà sì dá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:6 ni o tọ