Àwọn Ọba Keji 4:7 BM

7 Ó bá pada lọ sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún wolii Eliṣa. Eliṣa wí fún un pé, “Lọ ta àwọn òróró náà kí o sì san gbèsè rẹ ninu rẹ̀, kí ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ máa ná ìyókù.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:7 ni o tọ