Àwọn Ọba Keji 5:1 BM

1 Naamani, olórí ogun Siria, jẹ́ eniyan pataki ati ọlọ́lá níwájú ọba Siria, nítorí pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni OLUWA ṣe fún ilẹ̀ Siria ní ìṣẹ́gun. Ó jẹ́ akọni jagunjagun, ṣugbọn adẹ́tẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:1 ni o tọ