Àwọn Ọba Keji 5:2 BM

2 Iyawo Naamani ní iranṣẹbinrin kékeré kan tí àwọn ará Siria mú lẹ́rú wá láti ilẹ̀ Israẹli, nígbà tí wọ́n lọ bá wọn jagun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:2 ni o tọ