Àwọn Ọba Keji 6:28 BM

28 Ó bá bèèrè pé, “Kí ni ìṣòro rẹ?” Obinrin náà dáhùn, ó ní, “Obinrin yìí sọ fún mi pé kí n mú ọmọ mi wá kí á pa á jẹ, bí ó bá di ọjọ́ keji a óo pa ọmọ tirẹ̀ jẹ,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:28 ni o tọ