Àwọn Ọba Keji 6:29 BM

29 ni a bá pa ọmọ tèmi jẹ. Ní ọjọ́ keji, mo sọ fún un pé kí ó mú ọmọ tirẹ̀ wá kí á pa á jẹ, ṣugbọn ó fi ọmọ tirẹ̀ pamọ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:29 ni o tọ