Àwọn Ọba Keji 8:28 BM

28 Ahasaya bá Joramu, ọba Israẹli lọ, wọ́n gbógun ti Hasaeli, ọba Siria, ní Ramoti Gileadi. Àwọn ọmọ ogun Siria ṣá ọba Joramu lọ́gbẹ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:28 ni o tọ