Àwọn Ọba Keji 8:29 BM

29 Ó pada sí ìlú Jesireeli, ó lọ wo ọgbẹ́ náà sàn. Ahasaya, ọba Juda, ọmọ Jehoramu, sì lọ bẹ̀ ẹ́ wò ní Jesireeli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:29 ni o tọ