Àwọn Ọba Keji 9:2 BM

2 Nígbà tí o bá dé ibẹ̀, bèèrè Jehu, ọmọ Jehoṣafati, ọmọ Nimṣi; mú un wọ yàrá kan lọ kúrò láàrin àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:2 ni o tọ