3 Kí o da òróró inú ìgò yìí sí i lórí, kí o sì wí pé, OLUWA sọ pé, ‘Mo fi òróró yàn ọ́ ní ọba lórí Israẹli.’ Kí o sì yára sá kúrò níbẹ̀.”
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9
Wo Àwọn Ọba Keji 9:3 ni o tọ