Nehemaya 12:45 BM

45 Wọ́n ṣe ìsìn Ọlọrun ati ìsìn ìyàsímímọ́ bí àwọn akọrin ati àwọn olùṣọ́ ẹnu ọ̀nà tí ṣe, gẹ́gẹ́ bí òfin Dafidi ati ti ọmọ rẹ̀, Solomoni.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:45 ni o tọ