Nehemaya 4:19 BM

19 Mo sì sọ fún àwọn ọlọ́lá ati àwọn ìjòyè ati àwọn eniyan yòókù pé, “Iṣẹ́ náà pọ̀ gan-an, odi yìí sì gùn tóbẹ́ẹ̀ tí ó mú kí á jìnnà sí ara wa.

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:19 ni o tọ