Nehemaya 4:18 BM

18 Ẹnìkọ̀ọ̀kan ninu àwọn tí wọn ń ṣiṣẹ́ náà fi idà kọ́ èjìká bí ó ṣe ń mọ odi lọ. Ẹni tí ó ń fọn fèrè sì wà ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:18 ni o tọ