Nehemaya 9:12 BM

12 Ò ń fi ọ̀wọ̀n ìkùukùu darí wọn lọ́sàn-án, o sì ń fi ọ̀wọ̀n iná darí wọn lóru, ò ń tọ́ wọn sí ọ̀nà tí ó yẹ kí wọ́n rìn.

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:12 ni o tọ