Nehemaya 9:13 BM

13 O sọ̀kalẹ̀ sí orí òkè Sinai, o bá wọn sọ̀rọ̀ láti ọ̀run, o sì fún wọn ní ìlànà ati ìdájọ́ tí ó tọ̀nà ati àwọn òfin tòótọ́,

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:13 ni o tọ