14 O kọ́ wọn láti máa pa ọjọ́ ìsinmi rẹ mọ́, o sì tún pèsè ẹ̀kọ́, ìlànà, ati òfin fún wọn láti ọwọ́ Mose iranṣẹ rẹ.
Ka pipe ipin Nehemaya 9
Wo Nehemaya 9:14 ni o tọ