Nehemaya 9:20 BM

20 O fún wọn ní ẹ̀mí rere rẹ láti máa kọ́ wọn, o kò dá mana rẹ dúró, o fi ń bọ́ wọn. O sì ń fún wọn ni omi mu nígbà tí òùngbẹ bá ń gbẹ wọ́n.

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:20 ni o tọ