21 Ogoji ọdún ni o fi bọ́ wọn ninu aṣálẹ̀, wọn kò sì ṣe àìní ohunkohun, aṣọ wọn kò gbó, ẹsẹ̀ wọn kò sì wú.
Ka pipe ipin Nehemaya 9
Wo Nehemaya 9:21 ni o tọ