Orin Solomoni 1:3 BM

3 Òróró ìpara rẹ ní òórùn dídùn,orúkọ rẹ dàbí òróró ìkunra tí a tú jáde;nítorí náà ni àwọn ọmọbinrin ṣe fẹ́ràn rẹ.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 1

Wo Orin Solomoni 1:3 ni o tọ