Orin Solomoni 4:8 BM

8 Máa bá mi bọ̀ láti òkè Lẹbanoni, iyawo mi,máa bá mi bọ̀ láti òkè Lẹbanoni.Kúrò ní ṣóńṣó òkè Amana,kúrò lórí òkè Seniri ati òkè Herimoni,kúrò ninu ihò kinniun, ati ibi tí àwọn ẹkùn ń gbé.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 4

Wo Orin Solomoni 4:8 ni o tọ