Orin Solomoni 4:9 BM

9 O ti kó sí mi lẹ́mìí, arabinrin mi, iyawo mi,ẹ̀ẹ̀kan náà tí o ti ṣíjú wò mí,pẹlu nǹkan ọ̀ṣọ́ tí ó wà lọ́rùn rẹ,ni o ti kó sí mi lórí.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 4

Wo Orin Solomoni 4:9 ni o tọ