Samuẹli Keji 10:15 BM

15 Nígbà tí àwọn ará Siria rí i pé, àwọn ọmọ ogun Israẹli ti ṣẹgun àwọn, wọ́n kó gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn jọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 10

Wo Samuẹli Keji 10:15 ni o tọ